John 12:1

A fi ààmì òróró yàn Jesu ni Betani

1 aNítorí náà, nígbà tí àjọ ìrékọjá ku ọjọ́ mẹ́fà, Jesu wá sí Betani, níbi tí Lasaru wà, ẹni tí ó ti kú, tí Jesu jí dìde kúrò nínú òkú.
Copyright information for YorBMYO